5 Àwọn méjìlá (12) yìí ni Jésù rán jáde, ó fún wọn ní àwọn ìtọ́ni yìí:+ “Ẹ má lọ sí ojú ọ̀nà àwọn orílẹ̀-èdè, ẹ má sì wọ ìlú Samáríà kankan;+6 kàkà bẹ́ẹ̀, léraléra ni kí ẹ máa lọ sọ́dọ̀ àwọn àgùntàn ilé Ísírẹ́lì tó sọ nù.+
47 àti pé ní gbogbo orílẹ̀-èdè,+ bẹ̀rẹ̀ láti Jerúsálẹ́mù,+ a máa wàásù ní orúkọ rẹ̀ pé kí àwọn èèyàn ronú pìwà dà kí wọ́n lè rí ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀.+48 Ẹ máa jẹ́ ẹlẹ́rìí àwọn nǹkan yìí.+