-
Jeremáyà 5:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Wọn ò sì sọ lọ́kàn wọn pé:
“Ẹ jẹ́ ká bẹ̀rù Jèhófà Ọlọ́run wa,
Ẹni tó ń fúnni ní òjò ní àsìkò rẹ̀,
Òjò ìgbà ìkórè àti òjò ìgbà ìrúwé,
Ẹni tí kò jẹ́ kí àwọn ọ̀sẹ̀ ìkórè wa yẹ̀.”+
-