Ìṣe 16:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Nítorí náà, Pọ́ọ̀lù dé Déébè, ó sì dé Lísírà.+ Ọmọ ẹ̀yìn kan wà níbẹ̀ tó ń jẹ́ Tímótì,+ ọmọkùnrin obìnrin Júù kan tó jẹ́ onígbàgbọ́, àmọ́ Gíríìkì ni bàbá rẹ̀,
16 Nítorí náà, Pọ́ọ̀lù dé Déébè, ó sì dé Lísírà.+ Ọmọ ẹ̀yìn kan wà níbẹ̀ tó ń jẹ́ Tímótì,+ ọmọkùnrin obìnrin Júù kan tó jẹ́ onígbàgbọ́, àmọ́ Gíríìkì ni bàbá rẹ̀,