-
Jẹ́nẹ́sísì 35:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Jékọ́bù wá sọ fún agbo ilé rẹ̀ àti gbogbo àwọn tó wà pẹ̀lú rẹ̀ pé: “Ẹ mú àwọn ọlọ́run àjèjì tó wà láàárín yín+ kúrò, kí ẹ wẹ ara yín mọ́, kí ẹ pààrọ̀ aṣọ yín,
-
-
1 Kọ́ríńtì 10:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Nítorí náà, ẹ̀yin ará mi ọ̀wọ́n, ẹ sá fún ìbọ̀rìṣà.+
-