1 Tẹsalóníkà 1:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 1 Pọ́ọ̀lù, Sílífánù*+ àti Tímótì,+ sí ìjọ àwọn ará Tẹsalóníkà tó wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Ọlọ́run tó jẹ́ Baba àti Jésù Kristi Olúwa: Kí inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí àti àlàáfíà wà pẹ̀lú yín. 1 Pétérù 5:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Mo fi ọ̀rọ̀ díẹ̀ tí mo kọ yìí ránṣẹ́ sí yín nípasẹ̀ Sílífánù,*+ arákùnrin olóòótọ́, kí n lè fún yín níṣìírí, kí n sì lè jẹ́rìí taratara pé inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí tòótọ́ látọ̀dọ̀ Ọlọ́run nìyí. Ẹ dúró gbọn-in nínú rẹ̀.
1 Pọ́ọ̀lù, Sílífánù*+ àti Tímótì,+ sí ìjọ àwọn ará Tẹsalóníkà tó wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Ọlọ́run tó jẹ́ Baba àti Jésù Kristi Olúwa: Kí inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí àti àlàáfíà wà pẹ̀lú yín.
12 Mo fi ọ̀rọ̀ díẹ̀ tí mo kọ yìí ránṣẹ́ sí yín nípasẹ̀ Sílífánù,*+ arákùnrin olóòótọ́, kí n lè fún yín níṣìírí, kí n sì lè jẹ́rìí taratara pé inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí tòótọ́ látọ̀dọ̀ Ọlọ́run nìyí. Ẹ dúró gbọn-in nínú rẹ̀.