22 Lẹ́yìn náà, àwọn àpọ́sítélì àti àwọn alàgbà pẹ̀lú gbogbo ìjọ pinnu láti rán àwọn ọkùnrin tí wọ́n yàn láàárín wọn lọ sí Áńtíókù, pẹ̀lú Pọ́ọ̀lù àti Bánábà; wọ́n rán Júdásì tí wọ́n ń pè ní Básábà àti Sílà,+ àwọn tó ń mú ipò iwájú láàárín àwọn ará.
12 Mo fi ọ̀rọ̀ díẹ̀ tí mo kọ yìí ránṣẹ́ sí yín nípasẹ̀ Sílífánù,*+ arákùnrin olóòótọ́, kí n lè fún yín níṣìírí, kí n sì lè jẹ́rìí taratara pé inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí tòótọ́ látọ̀dọ̀ Ọlọ́run nìyí. Ẹ dúró gbọn-in nínú rẹ̀.