27 Ní tòótọ́, Hẹ́rọ́dù àti Pọ́ńtíù Pílátù+ pẹ̀lú àwọn èèyàn àwọn orílẹ̀-èdè àti àwọn èèyàn Ísírẹ́lì kóra jọ ní ìlú yìí láti dojú kọ Jésù, ìránṣẹ́ rẹ mímọ́, ẹni tí o fòróró yàn,+ 28 kí wọ́n lè ṣe àwọn ohun tí o ti pinnu nípasẹ̀ ọwọ́ rẹ àti ìmọ̀ràn rẹ pé kó ṣẹlẹ̀.+