Jòhánù 17:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Torí náà, ní báyìí, Baba, ṣe mí lógo lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ pẹ̀lú ògo tí mo ti ní lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ kí ayé tó wà.+ Éfésù 1:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 bí ó ṣe yàn wá láti wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú rẹ̀* ṣáájú ìgbà pípilẹ̀ ayé, kí a lè jẹ́ mímọ́, kí a sì wà láìní àbààwọ́n+ níwájú rẹ̀ nínú ìfẹ́.
5 Torí náà, ní báyìí, Baba, ṣe mí lógo lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ pẹ̀lú ògo tí mo ti ní lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ kí ayé tó wà.+
4 bí ó ṣe yàn wá láti wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú rẹ̀* ṣáájú ìgbà pípilẹ̀ ayé, kí a lè jẹ́ mímọ́, kí a sì wà láìní àbààwọ́n+ níwájú rẹ̀ nínú ìfẹ́.