Sáàmù 16:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Torí o ò ní fi mí sílẹ̀* nínú Isà Òkú.*+ O ò ní jẹ́ kí ẹni ìdúróṣinṣin rẹ rí kòtò.*+ Lúùkù 24:45, 46 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 45 Ó wá là wọ́n lóye ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ kí ìtúmọ̀ Ìwé Mímọ́ lè yé wọn,+ 46 ó sì sọ fún wọn pé: “Ohun tí a kọ nìyí: pé Kristi máa jìyà, ó sì máa dìde láàárín àwọn òkú ní ọjọ́ kẹta,+
45 Ó wá là wọ́n lóye ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ kí ìtúmọ̀ Ìwé Mímọ́ lè yé wọn,+ 46 ó sì sọ fún wọn pé: “Ohun tí a kọ nìyí: pé Kristi máa jìyà, ó sì máa dìde láàárín àwọn òkú ní ọjọ́ kẹta,+