Ìṣe 18:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Júù kan wà tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Àpólò,+ ọmọ ìbílẹ̀ Alẹkisáńdíríà, ó dé sí Éfésù; ọkùnrin sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ tó mọ Ìwé Mímọ́ dunjú ni. Ìṣe 18:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Ó bẹ̀rẹ̀ sí í fìgboyà sọ̀rọ̀ nínú sínágọ́gù, nígbà tí Pírísílà àti Ákúílà+ gbọ́ ọ̀rọ̀ rẹ̀, wọ́n mú un wọ àwùjọ wọn, wọ́n sì ṣàlàyé ọ̀nà Ọlọ́run fún un lọ́nà tó túbọ̀ péye. 1 Kọ́ríńtì 16:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Àwọn ìjọ tó wà ní Éṣíà kí yín. Ákúílà àti Pírísíkà pẹ̀lú ìjọ tó wà ní ilé wọn+ kí yín tayọ̀tayọ̀ nínú Olúwa. 2 Tímótì 4:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Bá mi kí Pírísíkà àti Ákúílà+ àti agbo ilé Ónẹ́sífórù.+
24 Júù kan wà tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Àpólò,+ ọmọ ìbílẹ̀ Alẹkisáńdíríà, ó dé sí Éfésù; ọkùnrin sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ tó mọ Ìwé Mímọ́ dunjú ni.
26 Ó bẹ̀rẹ̀ sí í fìgboyà sọ̀rọ̀ nínú sínágọ́gù, nígbà tí Pírísílà àti Ákúílà+ gbọ́ ọ̀rọ̀ rẹ̀, wọ́n mú un wọ àwùjọ wọn, wọ́n sì ṣàlàyé ọ̀nà Ọlọ́run fún un lọ́nà tó túbọ̀ péye.
19 Àwọn ìjọ tó wà ní Éṣíà kí yín. Ákúílà àti Pírísíkà pẹ̀lú ìjọ tó wà ní ilé wọn+ kí yín tayọ̀tayọ̀ nínú Olúwa.