Ìṣe 19:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Bọ́jọ́ ṣe ń gorí ọjọ́, Àpólò+ wà ní Kọ́ríńtì, Pọ́ọ̀lù gba àwọn agbègbè tó jìnnà sí òkun kọjá, ó sì wá sí Éfésù.+ Ó rí àwọn ọmọ ẹ̀yìn kan níbẹ̀, 1 Kọ́ríńtì 1:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ohun tí mo ní lọ́kàn ni pé, kálukú yín ń sọ pé: “Èmi jẹ́ ti Pọ́ọ̀lù,” “Èmi jẹ́ ti Àpólò,”+ “Èmi jẹ́ ti Kéfà,”* “Èmi jẹ́ ti Kristi.” 1 Kọ́ríńtì 3:5, 6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Kí wá ni Àpólò jẹ́? Kí sì ni Pọ́ọ̀lù jẹ́? Àwọn òjíṣẹ́+ tí ẹ tipasẹ̀ wọn di onígbàgbọ́, bí Olúwa ṣe fún kálukú láǹfààní. 6 Èmi gbìn,+ Àpólò bomi rin,+ àmọ́ Ọlọ́run ló mú kó máa dàgbà,
19 Bọ́jọ́ ṣe ń gorí ọjọ́, Àpólò+ wà ní Kọ́ríńtì, Pọ́ọ̀lù gba àwọn agbègbè tó jìnnà sí òkun kọjá, ó sì wá sí Éfésù.+ Ó rí àwọn ọmọ ẹ̀yìn kan níbẹ̀,
12 Ohun tí mo ní lọ́kàn ni pé, kálukú yín ń sọ pé: “Èmi jẹ́ ti Pọ́ọ̀lù,” “Èmi jẹ́ ti Àpólò,”+ “Èmi jẹ́ ti Kéfà,”* “Èmi jẹ́ ti Kristi.”
5 Kí wá ni Àpólò jẹ́? Kí sì ni Pọ́ọ̀lù jẹ́? Àwọn òjíṣẹ́+ tí ẹ tipasẹ̀ wọn di onígbàgbọ́, bí Olúwa ṣe fún kálukú láǹfààní. 6 Èmi gbìn,+ Àpólò bomi rin,+ àmọ́ Ọlọ́run ló mú kó máa dàgbà,