Ìṣe 15:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Lẹ́yìn ọjọ́ díẹ̀, Pọ́ọ̀lù sọ fún Bánábà pé: “Ní báyìí,* jẹ́ ká pa dà lọ bẹ àwọn ará wò ní gbogbo ìlú tí a ti kéde ọ̀rọ̀ Jèhófà,* ká lè rí bí wọ́n ṣe ń ṣe sí.”+
36 Lẹ́yìn ọjọ́ díẹ̀, Pọ́ọ̀lù sọ fún Bánábà pé: “Ní báyìí,* jẹ́ ká pa dà lọ bẹ àwọn ará wò ní gbogbo ìlú tí a ti kéde ọ̀rọ̀ Jèhófà,* ká lè rí bí wọ́n ṣe ń ṣe sí.”+