Jòhánù 19:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Àmọ́, nígbà tí àwọn olórí àlùfáà àti àwọn aláṣẹ rí i, wọ́n kígbe pé: “Kàn án mọ́gi! Kàn án mọ́gi!”*+ Pílátù sọ fún wọn pé: “Ẹ mú un fúnra yín, kí ẹ sì pa á,* torí èmi ò rí i pé ó jẹ̀bi kankan.”+
6 Àmọ́, nígbà tí àwọn olórí àlùfáà àti àwọn aláṣẹ rí i, wọ́n kígbe pé: “Kàn án mọ́gi! Kàn án mọ́gi!”*+ Pílátù sọ fún wọn pé: “Ẹ mú un fúnra yín, kí ẹ sì pa á,* torí èmi ò rí i pé ó jẹ̀bi kankan.”+