Ìṣe 25:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Wọ́n kàn ń ṣe awuyewuye pẹ̀lú rẹ̀ nípa ìjọsìn ọlọ́run àjúbàfún*+ wọn àti nípa ọkùnrin kan tó ń jẹ́ Jésù, tó ti kú ṣùgbọ́n tí Pọ́ọ̀lù ń tẹnu mọ́ pé ó wà láàyè.+
19 Wọ́n kàn ń ṣe awuyewuye pẹ̀lú rẹ̀ nípa ìjọsìn ọlọ́run àjúbàfún*+ wọn àti nípa ọkùnrin kan tó ń jẹ́ Jésù, tó ti kú ṣùgbọ́n tí Pọ́ọ̀lù ń tẹnu mọ́ pé ó wà láàyè.+