ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 5:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 “Aláyọ̀ ni yín tí àwọn èèyàn bá pẹ̀gàn yín,+ tí wọ́n ṣe inúnibíni sí yín,+ tí wọ́n sì parọ́ oríṣiríṣi ohun burúkú mọ́ yín nítorí mi.+

  • Ìṣe 16:20, 21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Wọ́n mú wọn dé ọ̀dọ̀ àwọn adájọ́ kéékèèké, wọ́n sọ pé: “Àwọn ọkùnrin yìí ń yọ ìlú wa lẹ́nu gan-an ni.+ Júù ni wọ́n, 21 wọ́n sì ń kéde àwọn àṣà tí kò bófin mu fún wa láti tẹ́wọ́ gbà tàbí láti máa tẹ̀ lé, bẹ́ẹ̀, wọ́n mọ̀ pé ará Róòmù ni wá.”

  • Ìṣe 17:6, 7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Nígbà tí wọn ò rí wọn, wọ́n wọ́ Jásónì àti àwọn arákùnrin kan lọ sọ́dọ̀ àwọn alákòóso ìlú, wọ́n ń pariwo pé: “Àwọn ọkùnrin tó ń dojú ilẹ̀ ayé tí à ń gbé dé* ti wá síbí o,+ 7 Jásónì sì gbà wọ́n lálejò. Gbogbo àwọn ọkùnrin yìí ló ń ta ko àwọn àṣẹ Késárì, tí wọ́n ń sọ pé ọba míì wà tó ń jẹ́ Jésù.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́