Lúùkù 23:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Torí náà, èrò rẹpẹtẹ náà gbéra, gbogbo wọn pátá, wọ́n sì mú un lọ sọ́dọ̀ Pílátù.+ 2 Wọ́n wá bẹ̀rẹ̀ sí í fẹ̀sùn kàn án+ pé: “A rí i pé ọkùnrin yìí fẹ́ dojú ìjọba ilẹ̀ wa dé, ó ní ká má ṣe san owó orí fún Késárì,+ ó sì ń pe ara rẹ̀ ní Kristi ọba.”+
23 Torí náà, èrò rẹpẹtẹ náà gbéra, gbogbo wọn pátá, wọ́n sì mú un lọ sọ́dọ̀ Pílátù.+ 2 Wọ́n wá bẹ̀rẹ̀ sí í fẹ̀sùn kàn án+ pé: “A rí i pé ọkùnrin yìí fẹ́ dojú ìjọba ilẹ̀ wa dé, ó ní ká má ṣe san owó orí fún Késárì,+ ó sì ń pe ara rẹ̀ ní Kristi ọba.”+