Jóẹ́lì 2:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Lẹ́yìn ìyẹn, èmi yóò tú ẹ̀mí mi + sára onírúurú èèyàn,Àwọn ọmọ yín lọ́kùnrin àti lóbìnrin yóò sì máa sọ tẹ́lẹ̀,Àwọn àgbà ọkùnrin yín yóò máa lá àlá. Àwọn ọ̀dọ́kùnrin yín yóò sì máa rí ìran.+ Mátíù 3:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ní tèmi, mò ń fi omi batisí yín torí pé ẹ ronú pìwà dà,+ àmọ́ ẹni tó ń bọ̀ lẹ́yìn mi lágbára jù mí lọ, ẹni tí mi ò tó bọ́ bàtà rẹ̀.+ Ẹni yẹn máa fi ẹ̀mí mímọ́+ àti iná+ batisí yín. Máàkù 1:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Mò ń fi omi batisí yín, àmọ́ ó máa fi ẹ̀mí mímọ́ batisí yín.”+
28 Lẹ́yìn ìyẹn, èmi yóò tú ẹ̀mí mi + sára onírúurú èèyàn,Àwọn ọmọ yín lọ́kùnrin àti lóbìnrin yóò sì máa sọ tẹ́lẹ̀,Àwọn àgbà ọkùnrin yín yóò máa lá àlá. Àwọn ọ̀dọ́kùnrin yín yóò sì máa rí ìran.+
11 Ní tèmi, mò ń fi omi batisí yín torí pé ẹ ronú pìwà dà,+ àmọ́ ẹni tó ń bọ̀ lẹ́yìn mi lágbára jù mí lọ, ẹni tí mi ò tó bọ́ bàtà rẹ̀.+ Ẹni yẹn máa fi ẹ̀mí mímọ́+ àti iná+ batisí yín.