Ìṣe 27:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Síbẹ̀, ní báyìí, mo rọ̀ yín pé kí ẹ mọ́kàn le, torí kò sí ìkankan* lára yín tó máa ṣègbé, àyàfi ọkọ̀ òkun yìí. 2 Kọ́ríńtì 11:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 ìgbà mẹ́ta ni wọ́n ti fi ọ̀pá nà mí,+ wọ́n sọ mí lókùúta lẹ́ẹ̀kan,+ ìgbà mẹ́ta ni mo ti wọkọ̀ tó rì,+ mo sì ti lo ọ̀sán kan àti òru kan lórí agbami òkun;
22 Síbẹ̀, ní báyìí, mo rọ̀ yín pé kí ẹ mọ́kàn le, torí kò sí ìkankan* lára yín tó máa ṣègbé, àyàfi ọkọ̀ òkun yìí.
25 ìgbà mẹ́ta ni wọ́n ti fi ọ̀pá nà mí,+ wọ́n sọ mí lókùúta lẹ́ẹ̀kan,+ ìgbà mẹ́ta ni mo ti wọkọ̀ tó rì,+ mo sì ti lo ọ̀sán kan àti òru kan lórí agbami òkun;