Ìṣe 27:41 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 41 Nígbà tí wọ́n fàyà gbá òkìtì kan lábẹ́ omi, tí omi n gba ẹ̀gbẹ́ rẹ̀ méjèèjì kọjá, ọkọ̀ wọn fàyà sọlẹ̀, iwájú ọkọ̀ fẹnu gúnlẹ̀, kò sì lè lọ mọ́, ni ìgbì bá bẹ̀rẹ̀ sí í fọ́ ìdí ọkọ̀ náà sí wẹ́wẹ́.+
41 Nígbà tí wọ́n fàyà gbá òkìtì kan lábẹ́ omi, tí omi n gba ẹ̀gbẹ́ rẹ̀ méjèèjì kọjá, ọkọ̀ wọn fàyà sọlẹ̀, iwájú ọkọ̀ fẹnu gúnlẹ̀, kò sì lè lọ mọ́, ni ìgbì bá bẹ̀rẹ̀ sí í fọ́ ìdí ọkọ̀ náà sí wẹ́wẹ́.+