Diutarónómì 18:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Jèhófà Ọlọ́run yín máa gbé wòlíì kan bí èmi dìde fún yín láàárín àwọn arákùnrin yín. Ẹ gbọ́dọ̀ fetí sí i.+ Diutarónómì 18:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Mo máa gbé wòlíì kan bíi tìẹ+ dìde fún wọn láàárín àwọn arákùnrin wọn, màá fi ọ̀rọ̀ mi sí i lẹ́nu,+ gbogbo ohun tí mo bá sì pa láṣẹ fún un ló máa sọ fún wọn.+
15 Jèhófà Ọlọ́run yín máa gbé wòlíì kan bí èmi dìde fún yín láàárín àwọn arákùnrin yín. Ẹ gbọ́dọ̀ fetí sí i.+
18 Mo máa gbé wòlíì kan bíi tìẹ+ dìde fún wọn láàárín àwọn arákùnrin wọn, màá fi ọ̀rọ̀ mi sí i lẹ́nu,+ gbogbo ohun tí mo bá sì pa láṣẹ fún un ló máa sọ fún wọn.+