Jẹ́nẹ́sísì 15:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ábúrámù ní ìgbàgbọ́ nínú Jèhófà,+ Ó sì kà á sí òdodo fún un.+ Jémíìsì 2:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 a sì mú ìwé mímọ́ náà ṣẹ tó sọ pé: “Ábúráhámù ní ìgbàgbọ́ nínú Jèhófà,* a sì kà á sí òdodo fún un,”+ a sì wá ń pè é ní ọ̀rẹ́ Jèhófà.*+
23 a sì mú ìwé mímọ́ náà ṣẹ tó sọ pé: “Ábúráhámù ní ìgbàgbọ́ nínú Jèhófà,* a sì kà á sí òdodo fún un,”+ a sì wá ń pè é ní ọ̀rẹ́ Jèhófà.*+