Ìṣe 5:41, 42 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 41 Torí náà, wọ́n jáde kúrò níwájú Sàhẹ́ndìrìn, wọ́n ń yọ̀+ nítorí a ti kà wọ́n yẹ láti jìyà nítorí orúkọ Jésù. 42 Lójoojúmọ́ nínú tẹ́ńpìlì àti láti ilé dé ilé,+ wọ́n ń kọ́ni láìdábọ̀, wọ́n sì ń kéde ìhìn rere nípa Kristi náà, Jésù.+
41 Torí náà, wọ́n jáde kúrò níwájú Sàhẹ́ndìrìn, wọ́n ń yọ̀+ nítorí a ti kà wọ́n yẹ láti jìyà nítorí orúkọ Jésù. 42 Lójoojúmọ́ nínú tẹ́ńpìlì àti láti ilé dé ilé,+ wọ́n ń kọ́ni láìdábọ̀, wọ́n sì ń kéde ìhìn rere nípa Kristi náà, Jésù.+