Hábákúkù 2:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Wo ẹni tó ń gbéra ga;*Kì í ṣe olóòótọ́ nínú ọkàn rẹ̀. Àmọ́ ìṣòtítọ́* yóò mú kí olódodo wà láàyè.+ Gálátíà 3:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Yàtọ̀ síyẹn, ó ṣe kedere pé kò sí ẹnì kankan tí a pè ní olódodo lọ́dọ̀ Ọlọ́run nípasẹ̀ òfin,+ nítorí “ìgbàgbọ́ yóò mú kí olódodo wà láàyè.”+ Hébérù 10:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 “Àmọ́ ìgbàgbọ́ yóò mú kí olódodo mi wà láàyè”+ àti pé “tó bá fà sẹ́yìn, inú mi* ò ní dùn sí i.”+
11 Yàtọ̀ síyẹn, ó ṣe kedere pé kò sí ẹnì kankan tí a pè ní olódodo lọ́dọ̀ Ọlọ́run nípasẹ̀ òfin,+ nítorí “ìgbàgbọ́ yóò mú kí olódodo wà láàyè.”+