Hábákúkù 2:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Wo ẹni tó ń gbéra ga;*Kì í ṣe olóòótọ́ nínú ọkàn rẹ̀. Àmọ́ ìṣòtítọ́* yóò mú kí olódodo wà láàyè.+ Róòmù 1:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Nítorí inú rẹ̀ ni a ti ń fi òdodo Ọlọ́run hàn nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ àti fún ìgbàgbọ́,+ gẹ́gẹ́ bó ṣe wà lákọsílẹ̀ pé: “Àmọ́ ìgbàgbọ́ yóò mú kí olódodo wà láàyè.”+ Hébérù 10:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 “Àmọ́ ìgbàgbọ́ yóò mú kí olódodo mi wà láàyè”+ àti pé “tó bá fà sẹ́yìn, inú mi* ò ní dùn sí i.”+
17 Nítorí inú rẹ̀ ni a ti ń fi òdodo Ọlọ́run hàn nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ àti fún ìgbàgbọ́,+ gẹ́gẹ́ bó ṣe wà lákọsílẹ̀ pé: “Àmọ́ ìgbàgbọ́ yóò mú kí olódodo wà láàyè.”+