Jòhánù 15:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ẹ wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú mi, màá sì wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú yín. Bí ẹ̀ka ò ṣe lè dá so èso àfi tó bá dúró lára àjàrà, ẹ̀yin náà ò lè ṣe bẹ́ẹ̀, àfi tí ẹ bá wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú mi.+
4 Ẹ wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú mi, màá sì wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú yín. Bí ẹ̀ka ò ṣe lè dá so èso àfi tó bá dúró lára àjàrà, ẹ̀yin náà ò lè ṣe bẹ́ẹ̀, àfi tí ẹ bá wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú mi.+