1 Kọ́ríńtì 15:53 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 53 Nítorí èyí tó lè bà jẹ́ gbọ́dọ̀ gbé àìdíbàjẹ́ wọ̀,+ èyí tó lè kú sì gbọ́dọ̀ gbé àìkú wọ̀.+ Ìfihàn 3:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Màá jẹ́ kí ẹni tó bá ṣẹ́gun+ jókòó pẹ̀lú mi lórí ìtẹ́ mi,+ bí èmi náà ṣe ṣẹ́gun, tí mo sì jókòó+ pẹ̀lú Baba mi lórí ìtẹ́ rẹ̀.
21 Màá jẹ́ kí ẹni tó bá ṣẹ́gun+ jókòó pẹ̀lú mi lórí ìtẹ́ mi,+ bí èmi náà ṣe ṣẹ́gun, tí mo sì jókòó+ pẹ̀lú Baba mi lórí ìtẹ́ rẹ̀.