-
Jẹ́nẹ́sísì 18:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Torí náà, ọ̀kan nínú wọn sọ pé: “Màá pa dà sọ́dọ̀ rẹ ní àkókò yìí lọ́dún tó ń bọ̀. Wò ó! Sérà ìyàwó rẹ yóò sì bí ọmọkùnrin+ kan.” Àmọ́ Sérà wà ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ tó wà lẹ́yìn ọkùnrin náà, ó ń gbọ́ ohun tí wọ́n ń sọ.
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 18:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Ǹjẹ́ a rí ohun tó pọ̀ jù fún Jèhófà+ láti ṣe? Màá pa dà sọ́dọ̀ rẹ ní àkókò yìí lọ́dún tó ń bọ̀, Sérà yóò sì bí ọmọkùnrin kan.”
-