Jóòbù 40:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Ṣó yẹ kí ẹni tó ń wá ẹ̀sùn bá Olódùmarè fa ọ̀rọ̀?+ Kí ẹni tó fẹ́ bá Ọlọ́run wí fèsì.”+