2 Kọ́ríńtì 7:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Nítorí náà, ẹ̀yin ẹni ọ̀wọ́n, nígbà tí a ti gba àwọn ìlérí yìí,+ ẹ jẹ́ kí a wẹ ara wa mọ́ kúrò nínú gbogbo ẹ̀gbin ti ara àti ti ẹ̀mí,+ kí a jẹ́ mímọ́ pátápátá nínú ìbẹ̀rù Ọlọ́run. 1 Pétérù 1:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 àmọ́ bíi ti Ẹni Mímọ́ tó pè yín, kí ẹ̀yin náà di mímọ́ nínú gbogbo ìwà yín,+
7 Nítorí náà, ẹ̀yin ẹni ọ̀wọ́n, nígbà tí a ti gba àwọn ìlérí yìí,+ ẹ jẹ́ kí a wẹ ara wa mọ́ kúrò nínú gbogbo ẹ̀gbin ti ara àti ti ẹ̀mí,+ kí a jẹ́ mímọ́ pátápátá nínú ìbẹ̀rù Ọlọ́run.