-
1 Tímótì 3:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 kí wọ́n ní ẹ̀rí ọkàn tó mọ́+ bí wọ́n ti ń rọ̀ mọ́ àṣírí mímọ́ ti ìgbàgbọ́.
-
-
1 Jòhánù 3:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Gbogbo ẹni tó bá sì ní ìrètí yìí nínú rẹ̀ ń wẹ ara rẹ̀ mọ́+ bí ẹni yẹn ṣe jẹ́ mímọ́.
-