Éfésù 3:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Mo di òjíṣẹ́ àṣírí mímọ́ yìí* nítorí inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí Ọlọ́run. Ó fún mi ní ẹ̀bùn ọ̀fẹ́ yìí nígbà tó fún mi ní agbára rẹ̀.+
7 Mo di òjíṣẹ́ àṣírí mímọ́ yìí* nítorí inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí Ọlọ́run. Ó fún mi ní ẹ̀bùn ọ̀fẹ́ yìí nígbà tó fún mi ní agbára rẹ̀.+