Àìsáyà 30:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Àmọ́ Jèhófà ń fi sùúrù dúró* láti ṣojúure sí yín,+Ó sì máa dìde láti ṣàánú yín.+ Torí pé Ọlọ́run ìdájọ́ òdodo ni Jèhófà.+ Aláyọ̀ ni gbogbo àwọn tó ń retí rẹ̀.*+
18 Àmọ́ Jèhófà ń fi sùúrù dúró* láti ṣojúure sí yín,+Ó sì máa dìde láti ṣàánú yín.+ Torí pé Ọlọ́run ìdájọ́ òdodo ni Jèhófà.+ Aláyọ̀ ni gbogbo àwọn tó ń retí rẹ̀.*+