ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Pétérù 2:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Torí ó dáa tí ẹnì kan bá fara da ìnira,* tó sì jìyà tí kò tọ́ sí i nítorí kó lè ní ẹ̀rí ọkàn rere lójú Ọlọ́run.+

  • 1 Pétérù 3:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Ẹ ní ẹ̀rí ọkàn rere,+ kó lè jẹ́ pé nínú ohunkóhun tí wọ́n bá ti sọ̀rọ̀ yín láìdáa, ìwà rere tí ẹ̀ ń hù torí ẹ jẹ́ ọmọlẹ́yìn Kristi+ máa jẹ́ kí ojú ti àwọn tó ń sọ̀rọ̀ yín láìdáa.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́