Mátíù 7:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 “Ẹ yéé dáni lẹ́jọ́,+ kí a má bàa dá yín lẹ́jọ́; Jémíìsì 4:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ẹnì kan ṣoṣo ni Afúnnilófin àti Onídàájọ́ wa,+ ẹni tó lè gbà là, tó sì lè pa run.+ Àmọ́ ìwọ, ta ni ọ́ tí o fi ń dá ọmọnìkejì rẹ lẹ́jọ́?+
12 Ẹnì kan ṣoṣo ni Afúnnilófin àti Onídàájọ́ wa,+ ẹni tó lè gbà là, tó sì lè pa run.+ Àmọ́ ìwọ, ta ni ọ́ tí o fi ń dá ọmọnìkejì rẹ lẹ́jọ́?+