1 Kọ́ríńtì 7:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ìdádọ̀dọ́* kò túmọ̀ sí nǹkan kan, àìdádọ̀dọ́* kò sì túmọ̀ sí nǹkan kan;+ pípa àwọn àṣẹ Ọlọ́run mọ́ ni ohun tó ṣe pàtàkì.+ Gálátíà 5:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Mo tún jẹ́rìí sí i pé dandan ni fún gbogbo ẹni tó bá dádọ̀dọ́* láti pa gbogbo Òfin mọ́.+
19 Ìdádọ̀dọ́* kò túmọ̀ sí nǹkan kan, àìdádọ̀dọ́* kò sì túmọ̀ sí nǹkan kan;+ pípa àwọn àṣẹ Ọlọ́run mọ́ ni ohun tó ṣe pàtàkì.+