1 Kọ́ríńtì 15:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Ẹ má ṣe jẹ́ kí ẹnikẹ́ni tàn yín jẹ. Ẹgbẹ́ búburú ń ba ìwà rere* jẹ́.+ Gálátíà 5:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ìwúkàrà díẹ̀ ló ń mú gbogbo ìṣùpọ̀ wú.+ 2 Tímótì 2:16, 17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Àmọ́ yẹra fún àwọn ọ̀rọ̀ asán tó ń ba ohun mímọ́ jẹ́,+ torí ṣe ló máa ń mú kí èèyàn túbọ̀ jìnnà sí Ọlọ́run, 17 ọ̀rọ̀ wọn sì máa tàn kálẹ̀ bí egbò tó kẹ̀. Híméníọ́sì àti Fílétọ́sì wà lára wọn.+
16 Àmọ́ yẹra fún àwọn ọ̀rọ̀ asán tó ń ba ohun mímọ́ jẹ́,+ torí ṣe ló máa ń mú kí èèyàn túbọ̀ jìnnà sí Ọlọ́run, 17 ọ̀rọ̀ wọn sì máa tàn kálẹ̀ bí egbò tó kẹ̀. Híméníọ́sì àti Fílétọ́sì wà lára wọn.+