Ìṣe 10:45 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 45 Ẹnu ya àwọn onígbàgbọ́* tó ti dádọ̀dọ́* tí wọ́n bá Pétérù wá, torí pé ẹ̀bùn ọ̀fẹ́ ẹ̀mí mímọ́ tú jáde sórí àwọn èèyàn orílẹ̀-èdè pẹ̀lú. Ìṣe 15:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Àwọn ọkùnrin kan wá láti Jùdíà, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ àwọn ará pé: “Láìjẹ́ pé ẹ dádọ̀dọ́* gẹ́gẹ́ bí àṣà tí Mósè fi lélẹ̀,+ ẹ ò lè rí ìgbàlà.” Ìṣe 15:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Nígbà tí a gbọ́ pé àwọn kan láàárín wa wá sọ́dọ̀ yín, tí wọ́n sì fi ọ̀rọ̀ tí wọ́n sọ kó wàhálà bá yín,+ tí wọ́n fẹ́ dojú yín* dé, bó tiẹ̀ jẹ́ pé a kò fún wọn ní àṣẹ kankan, Gálátíà 5:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ẹ wò ó! Èmi, Pọ́ọ̀lù, ń sọ fún yín pé tí ẹ bá dádọ̀dọ́,* Kristi ò ní ṣe yín láǹfààní kankan.+
45 Ẹnu ya àwọn onígbàgbọ́* tó ti dádọ̀dọ́* tí wọ́n bá Pétérù wá, torí pé ẹ̀bùn ọ̀fẹ́ ẹ̀mí mímọ́ tú jáde sórí àwọn èèyàn orílẹ̀-èdè pẹ̀lú.
15 Àwọn ọkùnrin kan wá láti Jùdíà, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ àwọn ará pé: “Láìjẹ́ pé ẹ dádọ̀dọ́* gẹ́gẹ́ bí àṣà tí Mósè fi lélẹ̀,+ ẹ ò lè rí ìgbàlà.”
24 Nígbà tí a gbọ́ pé àwọn kan láàárín wa wá sọ́dọ̀ yín, tí wọ́n sì fi ọ̀rọ̀ tí wọ́n sọ kó wàhálà bá yín,+ tí wọ́n fẹ́ dojú yín* dé, bó tiẹ̀ jẹ́ pé a kò fún wọn ní àṣẹ kankan,