ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Kọ́ríńtì 6:19, 20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Ṣé ẹ ò mọ̀ pé ara yín ni tẹ́ńpìlì+ ẹ̀mí mímọ́ tó wà nínú yín, èyí tí ẹ gbà lọ́wọ́ Ọlọ́run?+ Bákan náà, ẹ kì í ṣe ti ara yín,+ 20 nítorí a ti rà yín ní iye kan.+ Nítorí náà, ẹ máa yin Ọlọ́run lógo+ nínú ara yín.+

  • Hébérù 9:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Kì í ṣe ẹ̀jẹ̀ ewúrẹ́ àti ti àwọn akọ ọmọ màlúù ló gbé wọnú ibi mímọ́, àmọ́ ẹ̀jẹ̀ òun fúnra rẹ̀ ni,+ lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo láìtún ní ṣe é mọ́ láé, ó sì gba ìtúsílẹ̀* àìnípẹ̀kun fún wa.+

  • 1 Pétérù 1:18, 19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Torí ẹ mọ̀ pé kì í ṣe àwọn ohun tó lè bà jẹ́, bíi fàdákà tàbí wúrà la fi tú yín sílẹ̀,*+ kúrò nínú ìgbésí ayé asán tí àwọn baba ńlá yín fi lé yín lọ́wọ́.* 19 Ẹ̀jẹ̀ iyebíye ni,+ bí ẹ̀jẹ̀ ọ̀dọ́ àgùntàn tí kò ní àbààwọ́n, tí kò sì ní èérí kankan,+ ìyẹn ẹ̀jẹ̀ Kristi.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́