Àìsáyà 53:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Torí ìyẹn, màá fún un ní ìpín láàárín ọ̀pọ̀lọpọ̀,Ó sì máa pín ẹrù ogun pẹ̀lú àwọn alágbára,Torí ó tú ẹ̀mí* rẹ̀ jáde, àní títí dé ikú,+Wọ́n sì kà á mọ́ àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀;+Ó ru ẹ̀ṣẹ̀ ọ̀pọ̀ èèyàn,+Ó sì bá àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ bẹ̀bẹ̀.+ Hébérù 9:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 ǹjẹ́ ẹ̀jẹ̀ Kristi,+ ẹni tó tipasẹ̀ ẹ̀mí àìnípẹ̀kun fi ara rẹ̀ rúbọ sí Ọlọ́run láìní àbààwọ́n kò ní ṣe jù bẹ́ẹ̀ lọ láti wẹ ẹ̀rí ọkàn wa mọ́ kúrò nínú àwọn òkú iṣẹ́,+ ká lè máa ṣe iṣẹ́ ìsìn mímọ́ fún Ọlọ́run alààyè?+
12 Torí ìyẹn, màá fún un ní ìpín láàárín ọ̀pọ̀lọpọ̀,Ó sì máa pín ẹrù ogun pẹ̀lú àwọn alágbára,Torí ó tú ẹ̀mí* rẹ̀ jáde, àní títí dé ikú,+Wọ́n sì kà á mọ́ àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀;+Ó ru ẹ̀ṣẹ̀ ọ̀pọ̀ èèyàn,+Ó sì bá àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ bẹ̀bẹ̀.+
14 ǹjẹ́ ẹ̀jẹ̀ Kristi,+ ẹni tó tipasẹ̀ ẹ̀mí àìnípẹ̀kun fi ara rẹ̀ rúbọ sí Ọlọ́run láìní àbààwọ́n kò ní ṣe jù bẹ́ẹ̀ lọ láti wẹ ẹ̀rí ọkàn wa mọ́ kúrò nínú àwọn òkú iṣẹ́,+ ká lè máa ṣe iṣẹ́ ìsìn mímọ́ fún Ọlọ́run alààyè?+