Mátíù 10:9, 10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ẹ má ṣe wá wúrà, fàdákà tàbí bàbà sínú àmùrè tí ẹ̀ ń kó owó sí,+ 10 tàbí àpò oúnjẹ fún ìrìn àjò náà tàbí aṣọ méjì,* bàtà tàbí ọ̀pá,+ torí oúnjẹ tọ́ sí òṣìṣẹ́.+ Lúùkù 10:7, 8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Torí náà, ẹ dúró sínú ilé yẹn,+ kí ẹ jẹ, kí ẹ sì mu ohun tí wọ́n bá pèsè,+ torí owó iṣẹ́ tọ́ sí òṣìṣẹ́.+ Ẹ má ṣe máa ti ilé kan bọ́ sí òmíràn. 8 “Bákan náà, ibikíbi tí ẹ bá ti wọ ìlú kan, tí wọ́n sì gbà yín, ẹ jẹ ohun tí wọ́n bá gbé síwájú yín,
9 Ẹ má ṣe wá wúrà, fàdákà tàbí bàbà sínú àmùrè tí ẹ̀ ń kó owó sí,+ 10 tàbí àpò oúnjẹ fún ìrìn àjò náà tàbí aṣọ méjì,* bàtà tàbí ọ̀pá,+ torí oúnjẹ tọ́ sí òṣìṣẹ́.+
7 Torí náà, ẹ dúró sínú ilé yẹn,+ kí ẹ jẹ, kí ẹ sì mu ohun tí wọ́n bá pèsè,+ torí owó iṣẹ́ tọ́ sí òṣìṣẹ́.+ Ẹ má ṣe máa ti ilé kan bọ́ sí òmíràn. 8 “Bákan náà, ibikíbi tí ẹ bá ti wọ ìlú kan, tí wọ́n sì gbà yín, ẹ jẹ ohun tí wọ́n bá gbé síwájú yín,