Róòmù 8:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 torí ó dájú pé ẹ máa kú, tí ẹ bá ń gbé ìgbé ayé tara; àmọ́ tí ẹ bá fi ẹ̀mí lu àwọn iṣẹ́ tara pa,+ ẹ ó yè.+ Kólósè 3:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Nítorí náà, ẹ sọ àwọn ẹ̀yà ara yín+ tó wà láyé di òkú ní ti ìṣekúṣe,* ìwà àìmọ́, ìfẹ́ ìbálòpọ̀ tí kò níjàánu,+ ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ àti ojúkòkòrò, tó jẹ́ ìbọ̀rìṣà.
13 torí ó dájú pé ẹ máa kú, tí ẹ bá ń gbé ìgbé ayé tara; àmọ́ tí ẹ bá fi ẹ̀mí lu àwọn iṣẹ́ tara pa,+ ẹ ó yè.+
5 Nítorí náà, ẹ sọ àwọn ẹ̀yà ara yín+ tó wà láyé di òkú ní ti ìṣekúṣe,* ìwà àìmọ́, ìfẹ́ ìbálòpọ̀ tí kò níjàánu,+ ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ àti ojúkòkòrò, tó jẹ́ ìbọ̀rìṣà.