27 àmọ́ mò ń lu ara mi kíkankíkan,*+ mo sì ń darí rẹ̀ bí ẹrú, kó lè jẹ́ pé, lẹ́yìn tí mo bá ti wàásù fún àwọn ẹlòmíì, kí èmi fúnra mi má bàa di ẹni tí a kò tẹ́wọ́ gbà* lọ́nà kan ṣáá.
5 Nítorí náà, ẹ sọ àwọn ẹ̀yà ara yín+ tó wà láyé di òkú ní ti ìṣekúṣe,* ìwà àìmọ́, ìfẹ́ ìbálòpọ̀ tí kò níjàánu,+ ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ àti ojúkòkòrò, tó jẹ́ ìbọ̀rìṣà.