-
1 Kọ́ríńtì 8:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Nítorí bí ẹnì kan bá rí ìwọ tí o ní ìmọ̀ tí ò ń jẹun nínú tẹ́ńpìlì òrìṣà, ṣé kò ní mú kí ẹ̀rí ọkàn ẹni yẹn le débi pé á lọ jẹ oúnjẹ tí wọ́n fi rúbọ sí òrìṣà?
-