3 báwo la ṣe máa bọ́ tí a ò bá ka irú ìgbàlà tó tóbi bẹ́ẹ̀ sí? + Torí Olúwa wa bẹ̀rẹ̀ sí í sọ̀rọ̀ nípa rẹ̀,+ àwọn tó gbọ́ ọ lẹ́nu rẹ̀ sì fìdí rẹ̀ múlẹ̀ fún wa, 4 nígbà tí Ọlọ́run náà jẹ́rìí sí i pẹ̀lú àwọn iṣẹ́ àmì àti àwọn iṣẹ́ ìyanu àti oríṣiríṣi iṣẹ́ agbára,+ tó sì pín ẹ̀mí mímọ́ bó ṣe fẹ́.+