Éfésù 2:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 a sì ti kọ́ yín sórí ìpìlẹ̀ àwọn àpọ́sítélì àti àwọn wòlíì,+ nígbà tí Kristi Jésù fúnra rẹ̀ jẹ́ òkúta ìpìlẹ̀ igun ilé.+
20 a sì ti kọ́ yín sórí ìpìlẹ̀ àwọn àpọ́sítélì àti àwọn wòlíì,+ nígbà tí Kristi Jésù fúnra rẹ̀ jẹ́ òkúta ìpìlẹ̀ igun ilé.+