1 Kọ́ríńtì 12:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Ọlọ́run ti yan ẹnì kọ̀ọ̀kan sínú ìjọ: èkíní, àwọn àpọ́sítélì;+ èkejì, àwọn wòlíì;+ ẹ̀kẹta, àwọn olùkọ́;+ lẹ́yìn náà, àwọn iṣẹ́ agbára;+ lẹ́yìn náà, àwọn ẹ̀bùn ìwòsàn;+ àwọn iṣẹ́ ìrànwọ́; àwọn agbára láti máa darí+ àti oríṣiríṣi èdè.*+
28 Ọlọ́run ti yan ẹnì kọ̀ọ̀kan sínú ìjọ: èkíní, àwọn àpọ́sítélì;+ èkejì, àwọn wòlíì;+ ẹ̀kẹta, àwọn olùkọ́;+ lẹ́yìn náà, àwọn iṣẹ́ agbára;+ lẹ́yìn náà, àwọn ẹ̀bùn ìwòsàn;+ àwọn iṣẹ́ ìrànwọ́; àwọn agbára láti máa darí+ àti oríṣiríṣi èdè.*+