1 Pétérù 4:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ju gbogbo rẹ̀ lọ, ẹ ní ìfẹ́ tó jinlẹ̀ fún ara yín,+ torí ìfẹ́ máa ń bo ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀ṣẹ̀ mọ́lẹ̀.+