Òwe 10:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ìkórìíra ló ń dá awuyewuye sílẹ̀,Àmọ́ ìfẹ́ máa ń bo gbogbo àṣìṣe mọ́lẹ̀.+ Òwe 17:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ẹni tó bá ń dárí ẹ̀ṣẹ̀ jini* ń wá ìfẹ́,+Àmọ́ ẹni tó bá ń tẹnu mọ́ ọ̀rọ̀ ṣáá ń tú ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́ ká.+ 1 Kọ́ríńtì 13:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ìfẹ́+ máa ń ní sùúrù*+ àti inú rere.+ Ìfẹ́ kì í jowú,+ kì í fọ́nnu, kì í gbéra ga,+ 1 Kọ́ríńtì 13:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ó máa ń mú ohun gbogbo mọ́ra,+ ó máa ń gba ohun gbogbo gbọ́,+ ó máa ń retí ohun gbogbo,+ ó máa ń fara da ohun gbogbo.+
9 Ẹni tó bá ń dárí ẹ̀ṣẹ̀ jini* ń wá ìfẹ́,+Àmọ́ ẹni tó bá ń tẹnu mọ́ ọ̀rọ̀ ṣáá ń tú ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́ ká.+
7 Ó máa ń mú ohun gbogbo mọ́ra,+ ó máa ń gba ohun gbogbo gbọ́,+ ó máa ń retí ohun gbogbo,+ ó máa ń fara da ohun gbogbo.+