ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Kọ́ríńtì 12:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 A fún ẹnì kan ní ọ̀rọ̀ ọgbọ́n* nípasẹ̀ ẹ̀mí, a fún ẹlòmíì ní ọ̀rọ̀ ìmọ̀ nípasẹ̀ ẹ̀mí kan náà,

  • 1 Kọ́ríńtì 12:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 síbẹ̀, a fún òmíì ní ẹ̀bùn láti máa ṣe àwọn iṣẹ́ agbára,+ a fún òmíì ní ìsọtẹ́lẹ̀, a fún òmíì ní òye àwọn ọ̀rọ̀ onímìísí,+ a fún òmíì ní ẹ̀bùn oríṣiríṣi èdè,*+ a sì fún òmíì ní ìtúmọ̀ àwọn èdè.+

  • 1 Kọ́ríńtì 14:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Ní báyìí, ó wù mí kí gbogbo yín máa fi èdè fọ̀,*+ àmọ́ kí ẹ máa sọ tẹ́lẹ̀ ló wù mí jù.+ Ní tòótọ́, ẹni tó ń sọ tẹ́lẹ̀ tóbi ju ẹni tó ń fi èdè fọ̀, àfi tó bá ń túmọ̀* rẹ̀, kó lè máa gbé ìjọ ró.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́