ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Éfésù 3:5, 6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Ní àwọn ìran ìṣáájú, a kò fi àṣírí yìí han àwọn ọmọ èèyàn bí a ṣe fi han àwọn wòlíì àti àwọn àpọ́sítélì rẹ̀ mímọ́ nípasẹ̀ ẹ̀mí lásìkò yìí,+ 6 ìyẹn ni pé, nínú Kristi Jésù àti nípasẹ̀ ìhìn rere, kí àwọn èèyàn orílẹ̀-èdè lè di ajùmọ̀jogún, kí a jọ jẹ́ ẹ̀yà ara kan náà,+ kí a sì jọ pín nínú ìlérí náà.

  • Kólósè 2:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Èyí jẹ́ kí a lè tu ọkàn wọn lára,+ kí a lè so wọ́n pọ̀ di ọ̀kan nínú ìfẹ́,+ kí wọ́n sì lè ní gbogbo ọrọ̀ tó ń wá látinú òye wọn tó dájú hán-ún, kí wọ́n lè ní ìmọ̀ tó péye nípa àṣírí mímọ́ Ọlọ́run, ìyẹn Kristi.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́